Sáàmù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Dìde, Jèhófà! Gbà mí sílẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run mi! Nítorí wàá gbá gbogbo àwọn ọ̀tá mi ní páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́;Wàá ká eyín àwọn ẹni burúkú.+
7 Dìde, Jèhófà! Gbà mí sílẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run mi! Nítorí wàá gbá gbogbo àwọn ọ̀tá mi ní páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́;Wàá ká eyín àwọn ẹni burúkú.+