1 Tímótì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìdí nìyí tí a fi ń ṣiṣẹ́ kára, tí a sì ń sa gbogbo ipá wa,+ torí a ní ìrètí nínú Ọlọ́run alààyè, tó jẹ́ Olùgbàlà+ onírúurú èèyàn,+ ní pàtàkì àwọn olóòótọ́.
10 Ìdí nìyí tí a fi ń ṣiṣẹ́ kára, tí a sì ń sa gbogbo ipá wa,+ torí a ní ìrètí nínú Ọlọ́run alààyè, tó jẹ́ Olùgbàlà+ onírúurú èèyàn,+ ní pàtàkì àwọn olóòótọ́.