1 Tímótì 2:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+ 4 ẹni tó fẹ́ ká gba onírúurú èèyàn là,+ kí wọ́n sì ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́.
3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+ 4 ẹni tó fẹ́ ká gba onírúurú èèyàn là,+ kí wọ́n sì ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́.