ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 45:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ẹ yíjú sí mi, kí ẹ sì rí ìgbàlà,+ gbogbo ìkángun ayé.

      Torí èmi ni Ọlọ́run, kò sí ẹlòmíì.+

  • Ìṣe 17:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Lóòótọ́, Ọlọ́run ti gbójú fo ìgbà àìmọ̀ yìí;+ àmọ́ ní báyìí, ó ń sọ fún gbogbo èèyàn níbi gbogbo pé kí wọ́n ronú pìwà dà.

  • Róòmù 5:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nítorí náà, bó ṣe jẹ́ pé àṣemáṣe kan ló yọrí sí ìdálẹ́bi onírúurú èèyàn,+ bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe jẹ́ pé ìwà òdodo kan ló mú ká pe onírúurú èèyàn+ ní olódodo fún ìyè.+

  • 1 Tímótì 4:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ìdí nìyí tí a fi ń ṣiṣẹ́ kára, tí a sì ń sa gbogbo ipá wa,+ torí a ní ìrètí nínú Ọlọ́run alààyè, tó jẹ́ Olùgbàlà+ onírúurú èèyàn,+ ní pàtàkì àwọn olóòótọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́