Sáàmù 37:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀,Yóò gbé ọ ga láti jogún ayé. Nígbà tí a bá pa àwọn ẹni burúkú rẹ́,+ wàá rí i.+ Sáàmù 59:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run tó ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi yóò ràn mí lọ́wọ́;+Ọlọ́run yóò mú kí n rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.+
34 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀,Yóò gbé ọ ga láti jogún ayé. Nígbà tí a bá pa àwọn ẹni burúkú rẹ́,+ wàá rí i.+
10 Ọlọ́run tó ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi yóò ràn mí lọ́wọ́;+Ọlọ́run yóò mú kí n rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.+