Sáàmù 41:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kódà, ẹni tó wà ní àlàáfíà pẹ̀lú mi, tí mo fọkàn tán,+Ẹni tí a jọ ń jẹun, ti jìn mí lẹ́sẹ̀.*+ Mátíù 26:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nígbà tí wọ́n ń jẹun, ó sọ pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ọ̀kan nínú yín máa dà mí.”+ Jòhánù 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbogbo yín kọ́ ni mò ń bá wí; mo mọ àwọn tí mo ti yàn. Àmọ́ èyí jẹ́ torí kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ+ pé: ‘Ẹni tí a jọ ń jẹun ti jìn mí lẹ́sẹ̀.’*+
18 Gbogbo yín kọ́ ni mò ń bá wí; mo mọ àwọn tí mo ti yàn. Àmọ́ èyí jẹ́ torí kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ+ pé: ‘Ẹni tí a jọ ń jẹun ti jìn mí lẹ́sẹ̀.’*+