Sáàmù 91:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Yóò ké pè mí, màá sì dá a lóhùn.+ Màá dúró tì í nígbà wàhálà.+ Màá gbà á sílẹ̀, màá sì ṣe é lógo.