ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 119:147
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 147 Mo ti jí kí ilẹ̀ tó mọ́,* kí n lè kígbe fún ìrànlọ́wọ́,+

      Nítorí àwọn ọ̀rọ̀ rẹ ni ìrètí mi.*

  • Dáníẹ́lì 6:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́, gbàrà tí Dáníẹ́lì gbọ́ pé wọ́n ti fọwọ́ sí àṣẹ náà, ó lọ sínú ilé rẹ̀, èyí tí yàrá orí òrùlé rẹ̀ ní fèrèsé* tó ṣí sílẹ̀, tó kọjú sí ọ̀nà Jerúsálẹ́mù.+ Ẹ̀ẹ̀mẹta lójúmọ́ ló máa ń kúnlẹ̀ láti gbàdúrà, tó sì ń yin Ọlọ́run rẹ̀, bó ṣe máa ń ṣe ní gbogbo ìgbà ṣáájú àkókò yìí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́