Sáàmù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní òwúrọ̀, Jèhófà, wàá gbọ́ ohùn mi;+Ní òwúrọ̀, màá sọ ohun tó ń jẹ mí lọ́kàn fún ọ,+ màá sì dúró dè ọ́. Sáàmù 88:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Síbẹ̀, Jèhófà, mò ń ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́,+Àràárọ̀ ni àdúrà mi ń wá síwájú rẹ.+ Máàkù 1:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ní àárọ̀ kùtù, tí ilẹ̀ ò tíì mọ́, ó dìde, ó jáde lọ síbi tó dá, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà níbẹ̀.+
3 Ní òwúrọ̀, Jèhófà, wàá gbọ́ ohùn mi;+Ní òwúrọ̀, màá sọ ohun tó ń jẹ mí lọ́kàn fún ọ,+ màá sì dúró dè ọ́.