Sáàmù 55:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní alẹ́, ní òwúrọ̀ àti ní ọ̀sán, ìdààmú bá mi, mò ń kérora,*+Ó sì ń gbọ́ ohùn mi.+ Sáàmù 119:147 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 147 Mo ti jí kí ilẹ̀ tó mọ́,* kí n lè kígbe fún ìrànlọ́wọ́,+Nítorí àwọn ọ̀rọ̀ rẹ ni ìrètí mi.*