Sáàmù 55:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kí ìparun dé bá wọn!+ Kí wọ́n wọnú Isà Òkú* láàyè;Nítorí ìwà ibi wà láàárín wọn, ó sì ń gbé inú wọn.
15 Kí ìparun dé bá wọn!+ Kí wọ́n wọnú Isà Òkú* láàyè;Nítorí ìwà ibi wà láàárín wọn, ó sì ń gbé inú wọn.