Sáàmù 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wàá pa àwọn tó ń parọ́ run.+ Jèhófà kórìíra àwọn tó ń hu ìwà ipá àti ìwà ẹ̀tàn.*+ Òwe 10:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ìbẹ̀rù Jèhófà ń mú kí ẹ̀mí ẹni gùn,+Àmọ́ ọdún àwọn ẹni burúkú ni a ó gé kúrú.+