Róòmù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Kí ni ká wá sọ sọ́rọ̀ yìí? Tí Ọlọ́run bá wà lẹ́yìn wa, ta ló lè dènà wa?+