2 Kọ́ríńtì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó gbà wá sílẹ̀ látinú irú ewu ikú tó lágbára bẹ́ẹ̀, ó sì máa gbà wá sílẹ̀, òun la gbẹ́kẹ̀ lé pé á máa gbà wá sílẹ̀ nìṣó.+
10 Ó gbà wá sílẹ̀ látinú irú ewu ikú tó lágbára bẹ́ẹ̀, ó sì máa gbà wá sílẹ̀, òun la gbẹ́kẹ̀ lé pé á máa gbà wá sílẹ̀ nìṣó.+