Sáàmù 34:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Áńgẹ́lì Jèhófà pàgọ́ yí àwọn tó bẹ̀rù Rẹ̀ ká,+Ó sì ń gbà wọ́n sílẹ̀.+ Sáàmù 34:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìṣòro* olódodo máa ń pọ̀,+Àmọ́ Jèhófà ń gbà á sílẹ̀ nínú gbogbo rẹ̀.+ 2 Tímótì 4:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Olúwa máa gbà mí lọ́wọ́ gbogbo iṣẹ́ burúkú, ó sì máa pa mí mọ́ kí n lè wọ ìjọba rẹ̀ ní ọ̀run.+ Òun ni kí ògo jẹ́ tirẹ̀ títí láé àti láéláé. Àmín. 2 Pétérù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+
18 Olúwa máa gbà mí lọ́wọ́ gbogbo iṣẹ́ burúkú, ó sì máa pa mí mọ́ kí n lè wọ ìjọba rẹ̀ ní ọ̀run.+ Òun ni kí ògo jẹ́ tirẹ̀ títí láé àti láéláé. Àmín.
9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+