ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 34:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ìṣòro* olódodo máa ń pọ̀,+

      Àmọ́ Jèhófà ń gbà á sílẹ̀ nínú gbogbo rẹ̀.+

  • 1 Kọ́ríńtì 10:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kò sí àdánwò kankan tó ti bá yín àfi èyí tó máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn.+ Àmọ́ Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́, kò ní jẹ́ kí a dán yín wò kọjá ohun tí ẹ lè mú mọ́ra,+ ṣùgbọ́n nínú àdánwò náà, yóò ṣe ọ̀nà àbáyọ kí ẹ lè fara dà á.+

  • 2 Tímótì 4:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Olúwa máa gbà mí lọ́wọ́ gbogbo iṣẹ́ burúkú, ó sì máa pa mí mọ́ kí n lè wọ ìjọba rẹ̀ ní ọ̀run.+ Òun ni kí ògo jẹ́ tirẹ̀ títí láé àti láéláé. Àmín.

  • Ìfihàn 3:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí o pa ọ̀rọ̀ nípa ìfaradà mi mọ́,*+ màá pa ìwọ náà mọ́ nígbà wákàtí ìdánwò,+ èyí tó máa dé bá gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé, láti dán àwọn tó ń gbé ayé wò.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́