Oníwàásù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Mo tún ti rí i lábẹ́ ọ̀run* pé: Ìwà burúkú ti rọ́pò ìdájọ́ òdodo, ìwà burúkú sì ti rọ́pò òdodo.+ Míkà 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ jọ̀ọ́, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin olórí ilé Jékọ́bùÀti ẹ̀yin aláṣẹ ilé Ísírẹ́lì,+Tí ẹ kórìíra ìdájọ́ òdodo, tí ẹ sì ń yí gbogbo ọ̀rọ̀ po,+
9 Ẹ jọ̀ọ́, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin olórí ilé Jékọ́bùÀti ẹ̀yin aláṣẹ ilé Ísírẹ́lì,+Tí ẹ kórìíra ìdájọ́ òdodo, tí ẹ sì ń yí gbogbo ọ̀rọ̀ po,+