ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 27:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá ṣe èrú nínú ẹjọ́+ àjèjì, ọmọ aláìníbaba* tàbí opó.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)

  • Jeremáyà 5:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Wọ́n ti sanra, ara wọn sì ń dán;

      Iṣẹ́ ibi kún ọwọ́ wọn fọ́fọ́.

      Wọn kò gba ẹjọ́ ọmọ aláìníbaba rò,+

      Kí wọ́n lè ṣàṣeyọrí;

      Wọ́n ò fi òdodo dá ẹjọ́ àwọn aláìní.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́