-
Jeremáyà 23:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Wò ó! Ìjì Jèhófà máa fi ìbínú tú jáde;
Bí ìjì líle tó ń fẹ́ yí ká, á tú jáde sí orí àwọn ẹni burúkú.+