ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 25:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí:

      ‘Wò ó! Àjálù kan ń ṣẹlẹ̀ kiri láti orílẹ̀-èdè dé orílẹ̀-èdè,+

      A ó sì tú ìjì líle jáde láti ibi tó jìnnà jù lọ láyé.+

  • Jeremáyà 30:23, 24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Wò ó! Ìjì Jèhófà máa fi ìbínú tú jáde,+

      Ìjì líle tó ń gbá nǹkan lọ, tó sì ń tú jáde sórí àwọn ẹni burúkú.

      24 Ìbínú Jèhófà tó ń jó bí iná kò ní dáwọ́ dúró

      Títí á fi ṣe ohun tó wà lọ́kàn rẹ̀, tí á sì mú èrò rẹ̀ ṣẹ.+

      Ní àkókò òpin, ọ̀rọ̀ yìí á yé yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́