Sáàmù 33:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà ti mú kí ohun tí àwọn orílẹ̀-èdè gbèrò* já sí òfo;+Ó ti dojú ìmọ̀ràn* àwọn èèyàn dé.+