ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 15:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+

  • Diutarónómì 33:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  29 Aláyọ̀ ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì!+

      Ta ló dà bí rẹ,+

      Àwọn èèyàn tó ń gbádùn ìgbàlà Jèhófà,+

      Apata tó ń dáàbò bò ọ́,+

      Àti idà ọlá ńlá rẹ?

      Àwọn ọ̀tá rẹ máa ba búrúbúrú níwájú rẹ,+

      Wàá sì rìn lórí ẹ̀yìn* wọn.”

  • Sáàmù 3:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Àmọ́, ìwọ Jèhófà ni apata tó yí mi ká,+

      Ògo mi+ àti Ẹni tó ń gbé orí mi sókè.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́