-
Sáàmù 109:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Nítorí àwọn ẹni burúkú àti àwọn ẹlẹ́tàn ń la ẹnu wọn sí mi.
Wọ́n ń fi ahọ́n èké sọ̀rọ̀ nípa mi;+
-
Sáàmù 109:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kí àwọn ọmọ* rẹ̀ máa tọrọ nǹkan kiri,
Kí wọ́n sì máa jáde látinú ilé wọn tó ti di ahoro lọ wá oúnjẹ.
-
-
-