2 Sámúẹ́lì 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà tó yá, Dáfídì ṣẹ́gun àwọn Filísínì,+ ó borí wọn,+ Dáfídì sì gba Metegi-ámà lọ́wọ́ àwọn Filísínì.
8 Nígbà tó yá, Dáfídì ṣẹ́gun àwọn Filísínì,+ ó borí wọn,+ Dáfídì sì gba Metegi-ámà lọ́wọ́ àwọn Filísínì.