Sáàmù 63:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi,+Mo sì ń kígbe ayọ̀ lábẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ.+