Sáàmù 18:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,+Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.+ Sáàmù 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jèhófà, inú agbára rẹ ni ọba ti ń yọ̀;+Wo bí ó ṣe ń yọ̀ gidigidi nínú àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ!+ Sáàmù 21:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó béèrè ẹ̀mí lọ́wọ́ rẹ, o sì fún un,+Ẹ̀mí gígùn,* títí láé àti láéláé.
50 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,+Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.+