Sáàmù 40:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, má ṣe fawọ́ àánú rẹ sẹ́yìn lórí mi. Kí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ máa dáàbò bò mí nígbà gbogbo.+ Sáàmù 143:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Pa àwọn ọ̀tá mi rẹ́*+ nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀;Pa gbogbo àwọn tó ń halẹ̀ mọ́ mi* run,+Nítorí ìránṣẹ́ rẹ ni mí.+ Òwe 20:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ ń dáàbò bo ọba;+Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sì ń jẹ́ kó pẹ́ lórí ìtẹ́ rẹ̀.+
11 Jèhófà, má ṣe fawọ́ àánú rẹ sẹ́yìn lórí mi. Kí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ máa dáàbò bò mí nígbà gbogbo.+
12 Pa àwọn ọ̀tá mi rẹ́*+ nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀;Pa gbogbo àwọn tó ń halẹ̀ mọ́ mi* run,+Nítorí ìránṣẹ́ rẹ ni mí.+