Sáàmù 61:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wàá mú kí ẹ̀mí ọba gùn,*+Àwọn ọdún rẹ̀ yóò sì jẹ́ láti ìran dé ìran. 7 Yóò jókòó lórí ìtẹ́* níwájú Ọlọ́run títí láé;+Fún un ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́,* kí wọ́n lè máa dáàbò bò ó.+
6 Wàá mú kí ẹ̀mí ọba gùn,*+Àwọn ọdún rẹ̀ yóò sì jẹ́ láti ìran dé ìran. 7 Yóò jókòó lórí ìtẹ́* níwájú Ọlọ́run títí láé;+Fún un ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́,* kí wọ́n lè máa dáàbò bò ó.+