Sáàmù 37:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jèhófà máa ń darí ẹsẹ̀ ẹni*+Nígbà tí inú Rẹ̀ bá dùn sí ọ̀nà ẹni náà.+ 24 Bí onítọ̀hún bá tiẹ̀ ṣubú, kò ní balẹ̀ pátápátá,+Nítorí pé Jèhófà dì í lọ́wọ́ mú.*+ 2 Kọ́ríńtì 4:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọ́n há wa gádígádí ní gbogbo ọ̀nà, àmọ́ kò le débi tí a ò fi lè yíra; ọkàn wa dà rú, àmọ́ kì í ṣe láìsí ọ̀nà àbáyọ rárá;*+ 9 wọ́n ṣe inúnibíni sí wa, àmọ́ a ò pa wá tì;+ wọ́n gbé wa ṣánlẹ̀, àmọ́ a ò pa run.+
23 Jèhófà máa ń darí ẹsẹ̀ ẹni*+Nígbà tí inú Rẹ̀ bá dùn sí ọ̀nà ẹni náà.+ 24 Bí onítọ̀hún bá tiẹ̀ ṣubú, kò ní balẹ̀ pátápátá,+Nítorí pé Jèhófà dì í lọ́wọ́ mú.*+
8 Wọ́n há wa gádígádí ní gbogbo ọ̀nà, àmọ́ kò le débi tí a ò fi lè yíra; ọkàn wa dà rú, àmọ́ kì í ṣe láìsí ọ̀nà àbáyọ rárá;*+ 9 wọ́n ṣe inúnibíni sí wa, àmọ́ a ò pa wá tì;+ wọ́n gbé wa ṣánlẹ̀, àmọ́ a ò pa run.+