Sáàmù 36:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ mà ṣeyebíye o, Ọlọ́run!+ Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ ni àwọn ọmọ èèyàn fi ṣe ibi ààbò.+ Sáàmù 86:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ ní tìrẹ, Jèhófà, o jẹ́ Ọlọ́run aláàánú, tó ń gba tẹni rò,*Tí kì í tètè bínú, tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti òdodo* rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi.+ Míkà 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+
7 Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ mà ṣeyebíye o, Ọlọ́run!+ Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ ni àwọn ọmọ èèyàn fi ṣe ibi ààbò.+
15 Àmọ́ ní tìrẹ, Jèhófà, o jẹ́ Ọlọ́run aláàánú, tó ń gba tẹni rò,*Tí kì í tètè bínú, tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti òdodo* rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi.+
18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+