Sáàmù 103:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kì í fìgbà gbogbo wá àṣìṣe,+Kì í sì í bínú títí lọ.+ Àìsáyà 57:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí mi ò ní ta kò wọ́n títí láé,Mi ò sì ní máa bínú títí lọ;+Torí àárẹ̀ máa bá ẹ̀mí èèyàn nítorí mi,+Títí kan àwọn ohun tó ń mí, tí mo dá. Ìdárò 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ ni ò jẹ́ ká ṣègbé,+Nítorí àánú rẹ̀ kò ní dópin láé.+
16 Torí mi ò ní ta kò wọ́n títí láé,Mi ò sì ní máa bínú títí lọ;+Torí àárẹ̀ máa bá ẹ̀mí èèyàn nítorí mi,+Títí kan àwọn ohun tó ń mí, tí mo dá.