Àìsáyà 57:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí mi ò ní ta kò wọ́n títí láé,Mi ò sì ní máa bínú títí lọ;+Torí àárẹ̀ máa bá ẹ̀mí èèyàn nítorí mi,+Títí kan àwọn ohun tó ń mí, tí mo dá.
16 Torí mi ò ní ta kò wọ́n títí láé,Mi ò sì ní máa bínú títí lọ;+Torí àárẹ̀ máa bá ẹ̀mí èèyàn nítorí mi,+Títí kan àwọn ohun tó ń mí, tí mo dá.