-
Sáàmù 119:55Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
55 Jèhófà, mò ń rántí orúkọ rẹ ní òru,+
Kí n lè máa pa òfin rẹ mọ́.
-
55 Jèhófà, mò ń rántí orúkọ rẹ ní òru,+
Kí n lè máa pa òfin rẹ mọ́.