Sáàmù 63:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mo rántí rẹ lórí ibùsùn mi;Mò ń ṣe àṣàrò nípa rẹ nígbà ìṣọ́ òru.+ Lúùkù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nígbà yẹn, ó lọ sórí òkè lọ́jọ́ kan láti gbàdúrà,+ ó sì fi gbogbo òru gbàdúrà sí Ọlọ́run.+