Sáàmù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Nítorí ìnira àwọn tí ìyà ń jẹ,Nítorí ìkérora àwọn aláìní,+Màá dìde láti gbé ìgbésẹ̀,” ni Jèhófà wí. “Màá gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra wọn.”* Sáàmù 72:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí ó gbèjà* àwọn tó jẹ́ aláìní,Kí ó gba àwọn ọmọ òtòṣì là,Kí ó sì tẹ àwọn oníjìbìtì rẹ́.+
5 “Nítorí ìnira àwọn tí ìyà ń jẹ,Nítorí ìkérora àwọn aláìní,+Màá dìde láti gbé ìgbésẹ̀,” ni Jèhófà wí. “Màá gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra wọn.”*