-
Sáàmù 93:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
93 Jèhófà ti di Ọba!+
Ó gbé ọlá ńlá wọ̀ bí aṣọ;
Jèhófà gbé agbára wọ̀;
Ó fi di ara rẹ̀ bí àmùrè.
-
93 Jèhófà ti di Ọba!+
Ó gbé ọlá ńlá wọ̀ bí aṣọ;
Jèhófà gbé agbára wọ̀;
Ó fi di ara rẹ̀ bí àmùrè.