Sáàmù 104:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó ń mú kí koríko hù fún àwọn ẹran orí pápá láti jẹÀti ewéko fún ìlò aráyé,+Kí oúnjẹ lè jáde látinú ilẹ̀15 Àti wáìnì tó ń mú ọkàn èèyàn yọ̀,+Òróró tó ń mú kí ojú dánÀti oúnjẹ tó ń gbé ẹ̀mí ẹni kíkú ró.+
14 Ó ń mú kí koríko hù fún àwọn ẹran orí pápá láti jẹÀti ewéko fún ìlò aráyé,+Kí oúnjẹ lè jáde látinú ilẹ̀15 Àti wáìnì tó ń mú ọkàn èèyàn yọ̀,+Òróró tó ń mú kí ojú dánÀti oúnjẹ tó ń gbé ẹ̀mí ẹni kíkú ró.+