Sáàmù 147:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ kọrin sí Jèhófà pẹ̀lú ìdúpẹ́;Ẹ fi háàpù kọ orin ìyìn sí Ọlọ́run wa,8 Ẹni tó ń fi àwọsánmà bo ojú ọ̀run,Ẹni tó ń pèsè òjò fún ayé,+Ẹni tó ń mú kí koríko hù+ lórí àwọn òkè.
7 Ẹ kọrin sí Jèhófà pẹ̀lú ìdúpẹ́;Ẹ fi háàpù kọ orin ìyìn sí Ọlọ́run wa,8 Ẹni tó ń fi àwọsánmà bo ojú ọ̀run,Ẹni tó ń pèsè òjò fún ayé,+Ẹni tó ń mú kí koríko hù+ lórí àwọn òkè.