Sáàmù 10:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ Jèhófà, wàá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Wàá mú ọkàn wọn dúró ṣinṣin,+ wàá sì fiyè sí wọn.+ Mátíù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Aláyọ̀ ni àwọn oníwà tútù,*+ torí wọ́n máa jogún ayé.+
17 Àmọ́ Jèhófà, wàá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Wàá mú ọkàn wọn dúró ṣinṣin,+ wàá sì fiyè sí wọn.+