Sáàmù 72:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kí á yin orúkọ rẹ̀ ológo títí láé,+Kí ògo rẹ̀ sì kún gbogbo ayé.+ Àmín àti Àmín. Ìfihàn 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Jèhófà,* Ọlọ́run wa, ìwọ ló tọ́ sí láti gba ògo+ àti ọlá+ àti agbára,+ torí ìwọ lo dá ohun gbogbo,+ torí ìfẹ́ rẹ ni wọ́n ṣe wà, tí a sì dá wọn.”
11 “Jèhófà,* Ọlọ́run wa, ìwọ ló tọ́ sí láti gba ògo+ àti ọlá+ àti agbára,+ torí ìwọ lo dá ohun gbogbo,+ torí ìfẹ́ rẹ ni wọ́n ṣe wà, tí a sì dá wọn.”