1 Sámúẹ́lì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ń dáàbò bo ìṣísẹ̀ àwọn adúróṣinṣin rẹ̀,+Ṣùgbọ́n a ó pa àwọn ẹni burúkú lẹ́nu mọ́ nínú òkùnkùn,+Nítorí kì í ṣe nípa agbára ni èèyàn fi ń borí.+ Sáàmù 121:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ yọ̀.*+ Ẹni tó ń ṣọ́ ọ kò ní tòògbé láé.
9 Ó ń dáàbò bo ìṣísẹ̀ àwọn adúróṣinṣin rẹ̀,+Ṣùgbọ́n a ó pa àwọn ẹni burúkú lẹ́nu mọ́ nínú òkùnkùn,+Nítorí kì í ṣe nípa agbára ni èèyàn fi ń borí.+