Sáàmù 91:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ó máa pàṣẹ fún àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ nítorí rẹ,+Láti máa ṣọ́ ọ ní gbogbo ọ̀nà rẹ.+ 12 Wọ́n á fi ọwọ́ wọn gbé ọ,+Kí o má bàa fi ẹsẹ̀ rẹ gbá òkúta.+ Òwe 3:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nítorí Jèhófà yóò jẹ́ ìgbọ́kànlé rẹ;+Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ kó sí pańpẹ́.+
11 Torí ó máa pàṣẹ fún àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ nítorí rẹ,+Láti máa ṣọ́ ọ ní gbogbo ọ̀nà rẹ.+ 12 Wọ́n á fi ọwọ́ wọn gbé ọ,+Kí o má bàa fi ẹsẹ̀ rẹ gbá òkúta.+