Àìsáyà 63:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nínú gbogbo ìdààmú wọn, ìdààmú bá òun náà.+ Ìránṣẹ́ òun fúnra rẹ̀* sì gbà wọ́n là.+ Ó tún wọn rà nínú ìfẹ́ rẹ̀ àti ìyọ́nú rẹ̀,+Ó gbé wọn sókè, ó sì rù wọ́n ní gbogbo ìgbà àtijọ́.+
9 Nínú gbogbo ìdààmú wọn, ìdààmú bá òun náà.+ Ìránṣẹ́ òun fúnra rẹ̀* sì gbà wọ́n là.+ Ó tún wọn rà nínú ìfẹ́ rẹ̀ àti ìyọ́nú rẹ̀,+Ó gbé wọn sókè, ó sì rù wọ́n ní gbogbo ìgbà àtijọ́.+