Nọ́ńbà 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 tí ẹ sì mú nínú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran láti fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, ì bàá jẹ́ ẹbọ sísun+ tàbí ẹbọ tí ẹ rú láti san ẹ̀jẹ́ pàtàkì tàbí ọrẹ àtinúwá+ tàbí ọrẹ tí ẹ mú wá nígbà àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà+ yín láti mú òórùn dídùn* jáde sí Jèhófà,+
3 tí ẹ sì mú nínú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran láti fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, ì bàá jẹ́ ẹbọ sísun+ tàbí ẹbọ tí ẹ rú láti san ẹ̀jẹ́ pàtàkì tàbí ọrẹ àtinúwá+ tàbí ọrẹ tí ẹ mú wá nígbà àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà+ yín láti mú òórùn dídùn* jáde sí Jèhófà,+