Àìsáyà 42:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Ẹ yìn ín láti àwọn ìkángun ayé,+Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń lọ sínú òkun àti gbogbo ohun tó kún inú rẹ̀,Ẹ̀yin erékùṣù àti àwọn tó ń gbé inú wọn.+
10 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Ẹ yìn ín láti àwọn ìkángun ayé,+Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń lọ sínú òkun àti gbogbo ohun tó kún inú rẹ̀,Ẹ̀yin erékùṣù àti àwọn tó ń gbé inú wọn.+