Sáàmù 55:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ju ẹrù rẹ sọ́dọ̀ Jèhófà,+Yóò sì gbé ọ ró.+ Kò ní jẹ́ kí olódodo ṣubú* láé.+ 1 Pétérù 5:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ lábẹ́ ọwọ́ agbára Ọlọ́run, kó lè gbé yín ga ní àkókò tó yẹ,+ 7 ẹ máa kó gbogbo àníyàn* yín lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ torí ó ń bójú tó yín.*+
6 Torí náà, ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ lábẹ́ ọwọ́ agbára Ọlọ́run, kó lè gbé yín ga ní àkókò tó yẹ,+ 7 ẹ máa kó gbogbo àníyàn* yín lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ torí ó ń bójú tó yín.*+