Sáàmù 37:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jèhófà máa ń darí ẹsẹ̀ ẹni*+Nígbà tí inú Rẹ̀ bá dùn sí ọ̀nà ẹni náà.+ 24 Bí onítọ̀hún bá tiẹ̀ ṣubú, kò ní balẹ̀ pátápátá,+Nítorí pé Jèhófà dì í lọ́wọ́ mú.*+ Sáàmù 62:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní tòótọ́, òun ni àpáta mi àti ìgbàlà mi, ibi ààbò mi;*+Mìmì kan ò ní mì mí débi tí màá ṣubú.+ Sáàmù 121:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ yọ̀.*+ Ẹni tó ń ṣọ́ ọ kò ní tòògbé láé.
23 Jèhófà máa ń darí ẹsẹ̀ ẹni*+Nígbà tí inú Rẹ̀ bá dùn sí ọ̀nà ẹni náà.+ 24 Bí onítọ̀hún bá tiẹ̀ ṣubú, kò ní balẹ̀ pátápátá,+Nítorí pé Jèhófà dì í lọ́wọ́ mú.*+