Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+ Àìsáyà 45:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ Jèhófà máa gba Ísírẹ́lì là, ìgbàlà náà sì máa jẹ́ títí láé.+ Ojú ò ní tì yín, ìtìjú ò sì ní bá yín títí ayé.+
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+
17 Àmọ́ Jèhófà máa gba Ísírẹ́lì là, ìgbàlà náà sì máa jẹ́ títí láé.+ Ojú ò ní tì yín, ìtìjú ò sì ní bá yín títí ayé.+