-
Àwọn Onídàájọ́ 11:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Níkẹyìn, Jẹ́fútà dé sí ilé rẹ̀ ní Mísípà,+ wò ó! ọmọbìnrin rẹ̀ ló ń jáde bọ̀ wá pàdé rẹ̀, ó ń lu ìlù tanboríìnì, ó sì ń jó! Òun ni ọmọ kan ṣoṣo tó bí. Kò ní ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin míì.
-