Diutarónómì 32:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ẹ bá àwọn èèyàn+ rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,Torí ó máa gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Ó máa san àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lẹ́san,Ó sì máa ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀.”*
43 Ẹ bá àwọn èèyàn+ rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,Torí ó máa gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Ó máa san àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lẹ́san,Ó sì máa ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀.”*